Ifi 22
1 O si fi odò omi ìye kan han mi, ti o mọ́ bi kristali, ti nti ibi itẹ́ Ọlọrun ati ti Ọdọ-Agutan jade wá. 2 Li ãrin igboro rẹ̀, ati niha ikini keji odò na, ni igi iye gbé wà, ti ima so onirũru eso mejila, a si mã so eso rẹ̀ li oṣõṣù: ewé igi na si ni fún mimú awọn orilẹ-ède larada. 3 Ègún kì yio si si mọ́: itẹ́ Ọlọrun ati ti Ọdọ-Agutan ni yio si mã wà nibẹ̀; awọn iranṣẹ rẹ̀ yio si ma sìn i: 4 Nwọn o si mã ri oju rẹ̀; orukọ rẹ̀ yio si mã wà ni iwaju wọn.
5 Oru kì yio si si mọ́; nwọn kò si ni iwá imọlẹ fitila, tabi imọlẹ õrùn; nitoripe Oluwa Ọlọrun ni yio tan imọlẹ fun wọn: nwọn o si mã jọba lai ati lailai.Dídé Kristi
6 O si wi fun mi pe, ododo ati otitọ li ọ̀rọ wọnyi: Oluwa Ọlọrun ẹmi awọn woli li o si rán angẹli rẹ̀ lati fi ohun ti kò le ṣaiṣẹ kánkán hàn awọn iranṣẹ rẹ̀. 7 Kiyesi i, emi mbọ̀ kánkán: ibukún ni fun ẹniti npa ọ̀rọ isọtẹlẹ inu iwe yi mọ́. 8 Emi Johanu li ẹniti o gbọ́ ti o si ri nkan wọnyi. Nigbati mo si gbọ́ ti mo si ri, mo wolẹ lati foribalẹ niwaju ẹsẹ angẹli na, ti o fi nkan wọnyi hàn mi. 9 Nigbana li o wi fun mi pe, Wo o, máṣe bẹ̃: iranṣẹ ẹlẹgbẹ rẹ li emi, ati ti awọn arakunrin rẹ woli, ati ti awọn ti npa ọ̀rọ inu iwe yi mọ́: foribalẹ fun Ọlọrun. 10 O si wi fun mi pe, Máṣe fi èdidi dí ọ̀rọ isọtẹlẹ ti inu iwe yi: nitori ìgba kù si dẹ̀dẹ̀. 11 Ẹniti iṣe alaiṣõtọ, ki o mã ṣe alaiṣõtọ nṣó: ati ẹniti iṣe ẹlẹgbin, ki o mã ṣe ẹlẹgbin nṣó: ati ẹniti iṣe olododo, ki o mã ṣe olododo nṣó: ati ẹniti iṣe mimọ́, ki o mã ṣe mimọ́ nṣó. 12 Kiyesi i, emi mbọ̀ kánkán; ère mi si mbẹ pẹlu mi, lati san an fun olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ rẹ̀ yio ti ri. 13 Emi ni Alfa ati Omega, ẹni iṣaju ati ẹni ikẹhin, ipilẹṣẹ̀ ati opin. 14 Ibukún ni fun awọn ti nfọ̀ aṣọ wọn, ki nwọn ki o le ni anfani lati wá si ibi igi ìye na, ati ki nwọn ki o le gba awọn ẹnubode wọ inu ilu na. 15 Nitori li ode ni awọn ajá gbé wà, ati awọn oṣó, ati awọn àgbere, ati awọn apania, ati awọn abọriṣa, ati olukuluku ẹniti o fẹran eke ti o si nhuwa eke. 16 Emi Jesu li o rán angẹli mi lati jẹri nkan wọnyi fun nyin niti awọn ijọ. Emi ni gbòngbo ati iru-ọmọ Dafidi, ati irawọ owurọ̀ ti ntàn. 17 Ati Ẹmí ati iyawo wipe, Mã bọ̀. Ati ẹniti o ngbọ́ ki o wipe, Mã bọ̀. Ati ẹniti ongbẹ ngbẹ ki o wá. Ẹnikẹni ti o ba si fẹ, ki o gbà omi ìye na lọfẹ. 18 Emi njẹri fun olukuluku ẹniti o gbọ́ ọ̀rọ isọtẹlẹ iwe yi pe, Bi ẹnikẹni ba fi kún wọn, Ọlọrun yio fi kún awọn iyọnu ti a kọ sinu iwe yi fun u. 19 Bi ẹnikẹni ba si mu kuro ninu ọ̀rọ iwe isọtẹlẹ yi, Ọlọrun yio si mu ipa tirẹ̀ kuro ninu iwe ìye, ati kuro ninu ilu mimọ́ nì, ati kuro ninu awọn ohun ti a kọ sinu iwe yi. 20 Ẹniti o jẹri nkan wọnyi wipe, Nitõtọ emi mbọ̀ kánkán; Amin. Mã bọ̀, Jesu Oluwa. 21 Ore-ọfẹ Jesu Oluwa ki o wà pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́. Amin.11-Feb-2009@11:05, Backup Description=11-Feb-2009@09:10, Ayo Durodola -
08-Apr-2009@14:15, Backup Description=08-Apr-2009@08:23, Ayo Durodola -
08-Apr-2009@14:52, Backup Description=08-Apr-2009@14:37, Ayo Durodola -
22-Dec-2009@14:07, Backup Description=22-Dec-2009@14:01, victor Damilare -
Revelation 22
The River and the Tree of Life
1 Then he showed me a river of the water of life, clear as crystal, coming from the throne of God and of tthe Lamb,2 in the middle of its street. On either side of the river was the tree of life, bearing twelve t kinds of fruit, yielding its fruit every month; and the leaves of the tree were for the healing of the nations.3 There will no longer be any curse; and the throne of God and of the Lamb will be in it, and His bond-servants will serve Him;4 they will see His face, and His name will be on their foreheads.5 And there will no longer be any night; and they will not have need of the light of a lamp nor the light of the sun, because the Lord God will illumine them; and they will reign forever and ever.
6 And he said to me, "These words are faithful and true"; and the Lord, the God of the spirits of the prophets, sent His angel to show to His bond-servants the things which must soon take place.
7 "And behold, I am coming quickly. Blessed is he who heeds the words of the prophecy of this book."
8 I, John, am the one who heard and saw these things. And when I heard and saw, I fell down to worship at the feet of the angel who showed me these things.9 But he *said to me, "Do not do that. I am a fellow servant of yours and of your brethren the prophets and of those who heed the words of this book. Worship God."
The Final Message
10 And he *said to me, "Do not seal up the words of the prophecy of this book, for the time is near.11 Let the one who does wrong, still do wrong; and the one who is filthy, still be filthy; and let the one who is righteous, still practice righteousness; and the one who is holy, still keep himself holy."
12 "Behold, I am coming quickly, and My reward is with Me, to render to every man according to what he has done.13 I am the Alpha and the Omega, the first and the last, the beginning and the end."
14 Blessed are those who wash their robes, so that they may have the right to the tree of life, and may enter by the gates into the city.15 Outside are the dogs and the sorcerers and the immoral persons and the murderers and the idolaters, and everyone who loves and practices lying.
16 "I, Jesus, have sent My angel to testify to you these things for the churches. I am the root and the descendant of David, the bright morning star."
17 The Spirit and the bride say, "Come." And let the one who hears say, "Come." And let the one who is thirsty come; let the one who wishes take the water of life without cost.
18 I testify to everyone who hears the words of the prophecy of this book: if anyone adds to them, God will add to him the plagues which are written in this book;19 and if anyone takes away from the words of the book of this prophecy, God will take away his part from the tree of life and from the holy city, which are written in this book.
20 He who testifies to these things says, "Yes, I am coming quickly." Amen. Come, Lord Jesus.
21 The grace of the Lord Jesus be with tall. Amen.