Deep Dive 14

I. Joh 1

I. Joh 1

Ọ̀rọ̀ Ìyè

1 EYITI o ti wà li àtetekọṣe, ti awa ti gbọ́, ti awa ti fi oju wa ri, ti awa si ti tẹjumọ, ti ọwọ́ wa si ti dìmu, niti Ọrọ ìye; 2 (Ìye na si ti farahàn, awa si ti ri i, awa si njẹri, awa si nsọ ti ìye ainipẹkun na fun nyin, ti o ti mbẹ lọdọ Baba, ti o si farahàn fun wa;) 3 Eyiti awa ti ri, ti awa si ti gbọ́ li awa nsọ fun nyin, ki ẹnyin pẹlu ki o le ní ìdapọ pẹlu wa: nitõtọ ìdapọ wa si mbẹ pẹlu Baba, ati pẹlu Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi.

4 Awa si kọwe nkan wọnyi si nyin, ki ayọ̀ nyin ki o le di kikún.

Ìmọ́lẹ̀ ni Ọlọrun


5 Eyi si ni iṣẹ ti awa ti gbọ́ lẹnu rẹ̀ ti awa si njẹ́ fun nyin, pe imọlẹ li Ọlọrun, òkunkun kò si sí lọdọ rẹ̀ rara. 6 Bi awa ba wipe awa ní ìdapọ pẹlu rẹ̀, ti awa si nrìn ninu òkunkun, awa nṣeke, awa kò si ṣe otitọ: 7 Ṣugbọn bi awa ba nrìn ninu imọlẹ, bi on ti mbẹ ninu imọlẹ, awa ní ìdapọ pẹlu ara wa, ẹ̀jẹ Jesu Kristi Ọmọ rẹ̀ ni nwẹ̀ wa nù kuro ninu ẹṣẹ gbogbo. 8 Bi awa ba wipe awa kò li ẹ̀ṣẹ, awa tàn ara wa jẹ, otitọ kò si si ninu wa. 9 Bi awa ba jẹwọ ẹ̀ṣẹ wa, olõtọ ati olododo li on lati dari ẹṣẹ wa jì wa, ati lati wẹ̀ wa nù kuro ninu aiṣododo gbogbo. 10 Bi awa ba wipe awa kò dẹṣẹ̀, awa mu u li eke, ọ̀rọ rẹ̀ kò si si ninu wa.

Would you go skydiving without a parachute? Would you bungee jump without a bungee? Would you go on a roller coaster ride without pulling the shoulder harness down? Would you scuba dive with no air in the tanks? Could I convince you to eat a rotten egg with a dead goldfish in it, just for the fun of it? The answer to all these questions is a definite "NO!!!" That stuff isn't smart. It's not tempting. It's a no brainer! Why? Because participating in any of those activities would lead to pain for sure, and probably to death! Wanna know something crazy? Most teenagers take those kinds of chances every day. They may not be performing daredevil stunts or eating raw food, but they take the chance of living life on their own. God designed us in His image, as relational beings. He created us to be in a relationship with him and with other believers (1 John 1:3). In the Bible, Christians are never divided into those who go to church and those who don't. In the New Testament, wherever Christians were within range of each other, they met. In the book of Acts, every time the apostle Paul went to towns where there were new Christians, he immediately helped them meet with each other, and together they became a little church.

Pray that God would give you a heart for his people and that he would help you make the choice to meet consistently with other Christians.